Ológunàlà

Sísọ síta



Ìtumọọ Ológunàlà

The pure warrior; The warrior who fights for purity; The warrior of the white cloth.



Àwọn àlàyé mìíràn

A nickname for the warrior Ọlọ́fíngbémigùn from the town of Ìlárá-Mọ̀kín who fought in the Kírìjí war for the Èkìtì-Parapọ̀ confederacy



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ológun-àlà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ológun - warrior
àlà - white cloth, purity (symbol of Ọbàtálá)


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
AKURE