Okùríbidó
Sísọ síta
Ìtumọọ Okùríbidó
The god of wealth has found a place to rest.
Àwọn àlàyé mìíràn
"Okù", the Ìjẹ̀bú god of wealth corresponds to "Ajé" the Ọ̀yó Yorùbá god of business and enterprise.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
okù-rí-ibi-dó
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
Okù - the Ìjẹ̀bú god of wealth and successrí - find
ibi - place
dó - land, found, rest (tẹ̀dó)
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IJEBU