Okùbóyèjọ
Sísọ síta
Ìtumọọ Okùbóyèjọ
The god of wealth is at one with honour.
Àwọn àlàyé mìíràn
"Okù", the Ìjẹ̀bú god of wealth corresponds to "Ajé" the Ọ̀yó Yorùbá god of business and enterprise.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
òkú-bá-oyè-jọ
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
Okù - the Ìjẹ̀bú god of enterprisebá - together with
oyè - honour, chieftaincy
jọ - be at one with, be in cooperation with, be as prominent as
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IJEBU