Okùnatọ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Okùnatọ́
The rope/band of long life.
Àwọn àlàyé mìíràn
A chieftaincy title.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
okùn-atọ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
okùn - rope, thread, wealthatọ́ - long life; one that is straight, appropriate or right
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ONDO
EKITI