Ojúrere

Sísọ síta



Ìtumọọ Ojúrere

Favour. The favourite.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ojú-rere



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ojú - face
rere - good


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IJEBU