Ojúolúwatómiwò
Sísọ síta
Ìtumọọ Ojúolúwatómiwò
The eyes of God are sufficient to watch over me.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ojú-olúwa-tó-mi-wò
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ojú - eyes, faceolúwa - lord, God
tó - suffice for
mi - me
wò - watch over, look at
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL