Ojúlàárí
Sísọ síta
Ìtumọọ Ojúlàárí
The eyes are what we see.
Àwọn àlàyé mìíràn
The name comes from the aphorism "ojúlàárí akòrínú", meaning "We can only see the face/eyes, we can't see people's thoughts/inside."
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ojú-ni-à-á-rí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ojú - face, eyesni - is
à - we
á - can
rí - see
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL