Ojútaláyọ̀
Sísọ síta
Ìtumọọ Ojútaláyọ̀
My mockers are ashamed
Àwọn àlàyé mìíràn
This name is typically given to a child born either after a long wait, or after a major embarrassing event in the family.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ojú-ti-aláyọ̀
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ojú...tì - be ashamedaláyọ̀ - mockers (àwọn tí ó ń yọ̀ wá)
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL