Ogúntán

Sísọ síta



Ìtumọọ Ogúntán

The war is (now) over.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ogun-tán



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ogun - war(s)
tán - complete(ly), finish


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKO