Ogúnnòìkí
Sísọ síta
Ìtumọọ Ogúnnòìkí
Ògún has notability.
Àwọn àlàyé mìíràn
See also: Ògúnwùsì
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ògún-ní-òkìkí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ògún - Ògún, the Yorùbá god of ironní - to have
òkìkí - notability, fame, success
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IJEBU