Odùwọlé

Sísọ síta



Ìtumọọ Odùwọlé

Ifá entered the house.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

odù-wọ-ilé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

odù - Ifá corpus/priesthood
wọ - enter
ilé - home, house, household


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IJEBU