Odùsanwó

Sísọ síta



Ìtumọọ Odùsanwó

Ifá paid (for this child).



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

odù-san-owó



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

odù - Ifá corpus/text; Ifá divination; message of Ifá
san - pay, benefit
owó - money, cowries


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Sanwó