Odùsànyà
Sísọ síta
Ìtumọọ Odùsànyà
Ifá repaid my suffering.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
odù-sàn-ìyà
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
odù - Ifá divination/corpus/priesthoodsan - pay
ìyà - suffering
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IJEBU
OGUN
SAGAMU