Odùfowókẹ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Odùfowókẹ́
Ifá pampered with money.
Àwọn àlàyé mìíràn
See: Adéfowókẹ́, Ògúnfowókẹ́, etc
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
odù-fi-owó-kẹ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
odù - Ifá corpus/text; Ifá divination; message of Ifáfi - used
owó - money, cowries
kẹ́ - cherish, care for, pet
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IJEBU