Odùṣínà

Sísọ síta



Ìtumọọ Odùṣínà

Odù opened the way.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

odù-ṣí-ọ̀nà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

odù - Ifá corpus/text; Ifá divination; message of Ifá
ṣí - open, commission
ọ̀nà - road, lane, way, path


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Odùshínà

Ṣínà

Shínà