Odùṣakin
Sísọ síta
Ìtumọọ Odùṣakin
The Ifá corpus has made a brave warrior; Ifá showed bravery.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
odù-ṣe-akin
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
odù - Ifá corpusṣe - make, create
akin - valor, bravery, the brave one
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IJEBU