Odòlayé
Sísọ síta
Ìtumọọ Odòlayé
The world is a river.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
odò-ni-ayé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
odò - riverni - is
ayé - world, life
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Odòlayé Àrẹ̀mú
Yorùbá poet/recording artist