Oṣónáíyà
Sísọ síta
Ìtumọọ Oṣónáíyà
The sorcerer is bold.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
oṣó-ní-àyà
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
oṣó - sorcerer, Oṣó divinity of fertility and farming, òriṣa okoní...àyà - be bold
-
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OGUN