Oṣóbándé

Sísọ síta



Ìtumọọ Oṣóbándé

See: Ṣóbándé.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

oṣó-bá-n-dé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oṣó - sorcerer, Òrìṣaoko (fertility deity)
- together with, to meet
n - me
- arrive


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OGUN



Irúurú

Oshóbándé