Òrìṣáwálé

Sísọ síta



Ìtumọọ Òrìṣáwálé

Òrìṣà has come home.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

òrìṣà-wá-ilé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

òrìṣà - the òrìṣà; the Supreme sky deity
- to find
ilé - house, home


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ṣàwálé

Wálé