Òrìṣátómi

Sísọ síta



Ìtumọọ Òrìṣátómi

Òrìṣà is sufficient for me



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

òrìṣà-tó-mi



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

òrìṣà - the òrìṣà; the Supreme sky deity
- suffice for
mi - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ILESHA



Irúurú

Ọ̀ṣátómi

Tómi