Ònítirí

Sísọ síta



Ìtumọọ Ònítirí

1. As today is. 2. How is today?



Àwọn àlàyé mìíràn

Bí òní ti rí, ọla kò rí bẹ́ẹ̀.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

òní-ti-rí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

òni - today
ti - has
rí - appear


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKO