Òkúndalàyè
Sísọ síta
Ìtumọọ Òkúndalàyè
The dead became the living.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
òkún-di-alààyè
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
òkún - the dead (òkú)di - become
alààyè - the living
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ILESHA