Òkúdalàyè
Sísọ síta
Ìtumọọ Òkúdalàyè
The dead has become the living.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
òkú-di-alààyè
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
okú - the dead, corpsedì - become
alààyè - the living
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA