Òkèyínká

Sísọ síta



Ìtumọọ Òkèyínká

Hills surround me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

òkè-yí-n-ká



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

òkè - hills
yí...ká - surround
n - me (mi)


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Yínká