Ògúnyẹrí

Sísọ síta



Ìtumọọ Ògúnyẹrí

Ògún suits the head.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ògún-yẹ-orí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ògún - Ògún, Yorùbá god of iron, war, hunting, and technology
yẹ - to befit, to suit me, to be worthy of
orí - head, body


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI