Ògúnwùmíjù
Sísọ síta
Ìtumọọ Ògúnwùmíjù
I'm strongly attracted to Ògún.
Àwọn àlàyé mìíràn
See also: Akínwùmíjù
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ògún-wù-mí-jù
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ògún - Ògún, the Yorùbá god of ironwù - be attracted to
mí - me
jù - above all
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI
GENERAL