Ògúntúbẹ̀rù
Sísọ síta
Ìtumọọ Ògúntúbẹ̀rù
Ogun is worthy of being in awe of.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ògún-tú-bẹ̀rù
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ògún - Ògún, the Yorùbá god of irontú - is worth (tó)
bẹ̀rù - be scared of, be respectful of, have in awe
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
AKURE