Ògúnsàlákọ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Ògúnsàlákọ́
Ògún hangs the cloth of Ọbàtálá (Òrìṣàlá)
Àwọn àlàyé mìíràn
Àlà is usually a word meaning "pure" or "white" and is used by worshippers of Obatala, the god of the sky & creator of humans, who has a link to Ògún, who is considered the first òrìṣà
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
Ògún-so-àlà-kọ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
Ògún - god of Ironso - tie
àlà - white cloth (symbol of Ọbatala)
kọ́ - to hang
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL