Ògúnríbidó

Sísọ síta



Ìtumọọ Ògúnríbidó

Ògún (or Ògún's people/worshippers/adherent) has found a place to settle.



Àwọn àlàyé mìíràn

See also: Okùríbidó or Olúríbidó



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ògún-rí-ibi-(tẹ̀)dó



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

Ògún - the Yorùbá god of iron
rí - find, see
ibi - someplace, location, spot
dó - settle, establish


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL