Ògúnmọ́láyan
Sísọ síta
Ìtumọọ Ògúnmọ́láyan
Ògún struts with honor.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ògún-mú-ọlá-yan
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ògún - Ògún, the god of iron, technology, and warmú - hold onto, pick, bring
ọlá - honour, nobility, wealth, success, prestige
yan - to strut
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI