Ògúnmọ́láwá

Sísọ síta



Ìtumọọ Ògúnmọ́láwá

Ògún brought honour here.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ògún-mú...wá-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ògún - Ògún, Yorùbá god of iron, war, hunting, and technology
mú...wá - bring
ọlá - honour, prestige, wealth, nobility


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OWO



Irúurú

Mọ́láwá