Ògúngbilé
Sísọ síta
Ìtumọọ Ògúngbilé
Ògún fills the house.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ògún-gbà-ilé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ògún - Ògún, god of iron, war, hunting, and technologygbà - take, collect, receive, save
ilé - home, house, household
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IBADAN