Ògúngbémibádé
Sísọ síta
Ìtumọọ Ògúngbémibádé
Ògún brought me in contact with royalty.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ògún-gbé-mi-bá-adé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ògún - Ògún, the god of iron, technology, and wargbé - carry
mi - me
bá - together with, meet
adé - crown, royalty
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL