Ògúngbèjà

Sísọ síta



Ìtumọọ Ògúngbèjà

Ògún avenged (us).



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ògún-gbè-ìjà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ògún - Ògún, the god of iron
gbè - support, take side
ìjà - fighting, quarrel


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ògúngbìjà

Gbèjà

Gbìjà