Ògúngbàmí
Sísọ síta
Ìtumọọ Ògúngbàmí
1. Ògún saved me. 2. Ògún received me.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ògún-gbà-mí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ògún - Ògún, the Yorùbá god of irongbà - take, collect, receive, save
mí - me
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL