Ògúndíminíyì
Sísọ síta
Ìtumọọ Ògúndíminíyì
Ògún did not block my honor.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ògún-ùn-dí-mi-ní-iyì
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ògún - the god of ironùn - does not
dí - block
mi - me
ní - have
iyì - value, worth
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL
ILESHA