Ògúndàíní

Sísọ síta



Ìtumọọ Ògúndàíní

Ògún holds on to this. Ògún upholds this.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

Ògún-di...ní-èyí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

Ògún - Yorùbá god of iron
di...ní - to hold on to (di...mú), to support as in a pillar (di...mú)
èyí - this
-


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IJEBU