Ògúndẹ̀hìn

Sísọ síta



Ìtumọọ Ògúndẹ̀hìn

Ògún has become my destiny.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ògún-di-ẹ̀hìn



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ògún - Ògún, the Yorùbá god of iron
di - become
ẹ̀hìn - future (ẹ̀yìn)


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ogúndẹ̀yìn