Ògúnbíntán

Sísọ síta



Ìtumọọ Ògúnbíntán

Ògún gave birth to me complete.



Àwọn àlàyé mìíràn

See: Ọlábíntán, Olúbíntán, etc



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ògún-bí-n-tán



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ògún - Ògún, Yorùbá god of iron, war, hunting, and technology
- give birth to
n - me (mi)
tán - complete(ly), finish


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL