Ògúnṣúà

Sísọ síta



Ìtumọọ Ògúnṣúà

1. Ògún brought good fortune/celebration. 2. Also Ògúnṣúà is the title of the king of Modákẹ́kẹ́ (in Ọ̀sun State, Nigeria).



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ògún-ṣe-ùà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ògún - Yorùbá god of iron
ṣe - make
ùà - the society, a gathering, celebration


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ògúnṣuwà