Ògúnlékan

Sísọ síta



Ìtumọọ Ògúnlékan

Ògún has added one (more child).



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ògún-lé-ìkan



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ògún - Ògún, the god of iron, technology, and war
- be added to
ìkan - one


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OYO



Irúurú

Lékan