Òbísànyà

Sísọ síta



Ìtumọọ Òbísànyà

Parents paid for (my) suffering.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

òbí-san-ìyà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

òbí - parents
san - pay (back)
ìyà - suffering


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Sànyà