Nífiṣe
Sísọ síta
Ìtumọọ Nífiṣe
Needed (by God).
Àwọn àlàyé mìíràn
From Matthew 21: 3: Olúwanífiṣe: "And if any man say ought unto you, ye shall say, The Lord hath need of them; and straightway he will send them."
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ní-fi-ṣe
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ní - havefi - use (it)
ṣe - to do with
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IBADAN
IGBOMINA