Moyọ̀síreolúwa

Sísọ síta



Ìtumọọ Moyọ̀síreolúwa

I am glad for the goodness of God.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

mo-yọ̀-sí-ire-olúwa



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

mo - I
yọ̀ - rejoice
sí - into
ire - goodness
olúwa - lord, God


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OYO



Irúurú

Moyọ̀síre

Moyọ̀