Sísọ síta
I have seen joy.
See: Atiráyọ̀
mo-ti-rí-ayọ̀
Ó pọ̀ ní: EKITI
Ráyọ̀
Bóyá o tiẹ̀ ní ìtàn kan láti sọ fún wa nípa orúkọ yìí, tàbí fún wa ní ǹkan tí a ṣì kọ, tàbí fikún oun kan tí a kọ sílẹ̀.