Motẹlẹ̀ọlá
Sísọ síta
Ìtumọọ Motẹlẹ̀ọlá
I have stepped onto a ground/land of honor.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
mo-tẹ-ilẹ̀-ọlá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
mo - Itẹ - to step (on)
ilẹ̀ - ground
ọlá - honour, nobility, wealth, success, prestige
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA