Mosimilólú

Sísọ síta



Ìtumọọ Mosimilólú

I depend/rely on God.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

mo-sinmi-lé-olú



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

mo - I
sinmi - rely, rest, depend
lé - on
olú - lord, God, Olúwa


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Mosinmilólúwa

Mosimilólú

Sinmilólúwa

Similólúwa

Similólú

Sinmilólú

Sinmi

Simi