Moróyinìfẹ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Moróyinìfẹ́

I have seen the sweetness in love.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

mo-rí-oyin-ìfẹ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

mo - I
- see, find
oyin - honey, sweetness
ìfẹ́ - love


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL