Moróunfólúwa
Sísọ síta
Ìtumọọ Moróunfólúwa
I have found something (a child) to give to God.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
Mo-rí-oun-fún-olúwa
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
Mo - Irí - to see, to find
oun - something (child)
fún - for
olúwa - God, Lord
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL